Àìsáyà 43:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ti fihàn, mo gbàlà mo sì ti kédeÈmi, kì í sì í ṣe àwọn àjèjì òrìṣà láàrin yín.Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí mi,” ni Olúwa wí,“Pé Èmi ni Ọlọ́run.

Àìsáyà 43

Àìsáyà 43:2-21