Àìsáyà 42:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi, Olúwa, ti pè ọ́ ní òdodo;Èmi yóò di ọwọ́ọ̀ rẹ mú.Èmi yóò pa ọ́ mọ́, n ó sì ṣe ọ́láti jẹ́ májẹ̀mú fún àwọn ènìyànàti ìmọ́lẹ̀ fún àwọn aláìkọlà

Àìsáyà 42

Àìsáyà 42:1-12