Àìsáyà 42:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun kì yóò kọsẹ̀ bẹ́ẹ̀ ni kò ní rẹ̀wẹ̀sìtítí tí yóò fi fi ìdájọ́ mulẹ̀ ní ayé.Nínú òfin rẹ̀ ni àwọn erékùṣù yóò fi ìrètíi wọn sí.”

Àìsáyà 42

Àìsáyà 42:2-13