Àìsáyà 42:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Fún ìgbà pípẹ́ ni mo ti dákẹ́ jẹ́ẹ́,mo ti wà ní ìdákẹ́ jẹ́ẹ́, mo sì kó ara ró.Ṣùgbọ́n ní àkókò yìí, gẹ́gẹ́ bí obìnrin tí ó ń rọbí,mo ṣunkún, mo sì ń mí hẹlẹ hẹlẹ.

Àìsáyà 42

Àìsáyà 42:13-20