Àìsáyà 41:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn erékùsù ti rí i wọ́n bẹ̀rù;ìpẹ̀kun ilẹ̀ ayé wárìrì.Wọ́n súnmọ́tòsí wọ́n sì wá síwájú

Àìsáyà 41

Àìsáyà 41:1-11