Àìsáyà 41:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ẹ sọ fún wa ohun ti ọjọ́ iwájú mú dáníkí àwa kí ó lè mọ̀ pé Ọlọ́run niyín.Ẹ ṣe nǹkankan, ìbáà ṣe rere tàbí búburú,tó bẹ́ẹ̀ tí àyà yóò fi fò wá tí ẹ̀rù yóò sì fi kún inú wa.

Àìsáyà 41

Àìsáyà 41:13-29