Àìsáyà 41:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò fi sínú aṣálẹ̀igi kédárì àti akaṣíà, mítílì àti ólífì.Èmi yóò da páínì sí inú ilẹ̀ síṣá,igi fíri àti ṣípírẹ́ṣì papọ̀

Àìsáyà 41

Àìsáyà 41:12-22