Àìsáyà 41:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ yóò fẹ́ wọn, afẹ́fẹ́ yóò sì gbá wọn mú,àti ẹ̀fúùfù yóò sì gbá wọn dànùṢùgbọ́n ìwọ yóò yọ̀ nínú Olúwaìwọ yóò sì ṣògo nínú Ẹni Mímọ́ ti Ísírẹ́lì.

Àìsáyà 41

Àìsáyà 41:15-26