Àìsáyà 40:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Koríko ń rọ ìtànná sì ń rẹ̀,ṣùgbọ́n ọ̀rọ̀ Ọlọ́run wa dúró títí láé.”

Àìsáyà 40

Àìsáyà 40:6-14