Àìsáyà 40:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àfonífojì ni a ó gbé ṣókè,gbogbo òkè ńlá àti òkè kékeré ni yóò di pẹ̀tẹ́lẹ̀;wíwọ́ ni a ó sọ di títọ́ àtiọ̀nà pálapàla ni a yóò sọ di títẹ́jú pẹrẹṣẹ,

Àìsáyà 40

Àìsáyà 40:1-10