Àìsáyà 40:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àní àwọn ọ̀dọ́ ń rẹ̀wẹ̀sì, ó ń rẹ̀ wọ́n,àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin sì ń kọsẹ̀ wọ́n ṣubú;

Àìsáyà 40

Àìsáyà 40:26-31