Àìsáyà 40:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níwájúù rẹ ni gbogbo orílẹ̀ èdè dàbí ohun tí kò sí;gbogbo wọn ló kà sí ohun tí kò wúlòtí kò tó ohun tí kò sí.

Àìsáyà 40

Àìsáyà 40:7-25