Àìsáyà 40:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni Olúwa ké sí kí ó là á lọ́yẹàti ta ni ó kọ́ òun ní ọ̀nà tí ó tọ́?Ta ni ẹni náà tí ó kọ́ ọ ní ọgbọ́ntàbí tí ó fi ipa ọ̀nà òye hàn án?

Àìsáyà 40

Àìsáyà 40:12-20