Àìsáyà 39:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àsìkò ń bọ̀ nítòótọ́ nígbà tí gbogbo ohun tí ó wà nínú ààfin rẹ, àti ohun gbogbo tí àwọn baba rẹ ti kó jọ títí di ọjọ́ òní yóò di kíkólọ sí Bábílónì. Ohun kankan kò ní ṣẹ́kù ni Olúwa wí.

Àìsáyà 39

Àìsáyà 39:1-8