“Lọ kí o sì sọ fún Heṣekáyà pé, ‘Ohun tí Olúwa wí nìyìí, Ọlọ́run Dáfídì baba rẹ sọ pé: Èmi ti gbọ́ àdúrà rẹ mo sì ti rí omijé rẹ; Èmi yóò fi ọdún mẹ́ẹ̀dógún kún ọjọ́ ayé rẹ.