Àìsáyà 38:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa, nípa nǹkan báwọ̀nyí ni àwọn ènìyàn ń gbé;àti pé ẹ̀mí mi rí iyè nínú un wọn pẹ̀lú.Ìwọ dá ìlera mi padàkí o sì jẹ́ kí n wà láàyè

Àìsáyà 38

Àìsáyà 38:9-18