Àìsáyà 38:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi wí pé, “Èmi kì yóò lè tún rí Olúwa mọ́,àni Olúwa, ní ilẹ̀ àwọn alààyè;èmi kì yóò lè síjú wo ọmọnìyàn mọ́,tàbí kí n wà pẹ̀lú àwọn tí ó sì ńgbe orílẹ̀ ayé báyìí.

Àìsáyà 38

Àìsáyà 38:8-13