Àìsáyà 37:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa àwọn oníṣẹ́ rẹìwọ ti mú àbùkù bá Olúwa.Ìwọ sì ti sọ wí pé‘pẹ̀lú àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin miÈmi ti gun orí òkè ńlá ńlá,ibi gíga jùlọ ti Lébánónì.Èmi ti gé igi kédárì rẹ tí ó ga jùlọ lulẹ̀,àti àyànfẹ́ igi páínì.Èmi ti dé ibi rẹ̀ tí ó ga jùlọ,igbó rẹ̀ tí ó dára jùlọ.

Àìsáyà 37

Àìsáyà 37:23-34