Àìsáyà 37:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun sì rán Eliákímù alákoṣo ààfin, Ṣébínà akọ̀wé, àti aṣíwájú àwọn àlùfáà, gbogbo wọn nínú aṣọ ọ̀fọ̀ lọ sí ọ̀dọ̀ Wòlíì Àìṣáyà ọmọ Ámósì.

Àìsáyà 37

Àìsáyà 37:1-9