Àìsáyà 37:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n ti da àwọn òrìṣà wọn sínú iná wọ́n sì ti pa wọ́n run, nítorí àwọn wọ̀nyí kì í ṣe ọlọ́run bí kò ṣe igi àti òkúta lásán, tí a ti ọwọ́ ènìyàn ṣe.

Àìsáyà 37

Àìsáyà 37:12-24