Àìsáyà 36:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Eliákímù ọmọ Hílíkáyà alábojútó ààfin, Ṣébínà akọ̀wé, àti Jóà ọmọ Áṣáfù akọ̀wé jáde lọ pàdé rẹ̀.

Àìsáyà 36

Àìsáyà 36:1-5