Àìsáyà 36:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà ni ọ̀gágun náà dìde tí ó sì ké sítà ní èdè Hébérù pé, “Ẹ gbọ́ àwọn ọ̀rọ̀ ọba ńlá, ọba Ásíríà!

Àìsáyà 36

Àìsáyà 36:4-15