Àìsáyà 35:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sọ fún àwọn oníbẹ̀rù ọkàn pé“Ẹ ṣe gírí, ẹ má bẹ̀rù;Ọlọ́run yín yóò wá,òun yóò wá pẹ̀lú ìgbẹ̀ṣan;pẹ̀lú ìgbẹ̀ṣan mímọ́òun yóò wá láti gbà yín là.”

Àìsáyà 35

Àìsáyà 35:1-10