Àìsáyà 35:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Aṣálẹ̀ àti ìyàngbẹ ilẹ̀ ni inú rẹ̀ yóò dùn;ihà yóò ṣe àjọyọ̀ yóò sì kún fún ìtànná.Gẹ́gẹ́ bí ewéko kúrókúsì,

Àìsáyà 35

Àìsáyà 35:1-10