Àìsáyà 34:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Idà Olúwa kún fún ẹ̀jẹ̀a mú un ṣanra fún ọ̀rá,àti fún ẹ̀jẹ̀ ọ̀dọ́-agùtàn àti ewurẹ,fún ọ̀rá iwe àgbò—nítorí Olúwa ni ìrúbọ kan ní Bósírà,àti ìpakúpa ńlá kan ní ilẹ̀ Édómù.

Àìsáyà 34

Àìsáyà 34:1-14