Àìsáyà 34:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ibínú Olúwa ń bẹlára gbogbo orílẹ̀-èdè,àti irunú un rẹ̀ lórí gbogbo ogun wọn:o ti fi wọ́n fún pipa,

Àìsáyà 34

Àìsáyà 34:1-10