Àìsáyà 34:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ki yóò paá ní òru tàbí ní ọ̀sán,èéfín rẹ̀ yóò gòkè láéláé:yóò dahoro láti ìran dé ìran,kò sí ẹnìkan tí yóò là á kọjá láéàti láéláé.

Àìsáyà 34

Àìsáyà 34:8-16