Àìsáyà 34:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Súnmọ́ tòsí,ẹ̀yin orílẹ̀-èdè láti gbọ́,tẹ́tísílẹ̀ ẹyín ènìyànjẹ́ kí ayé gbọ́,àti ẹ̀kún rẹ̀,ayé àti ohun gbogbo tí ó ti inú un rẹ̀ jáde.

2. Nítorí ibínú Olúwa ń bẹlára gbogbo orílẹ̀-èdè,àti irunú un rẹ̀ lórí gbogbo ogun wọn:o ti fi wọ́n fún pipa,

Àìsáyà 34