Àìsáyà 34:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Súnmọ́ tòsí,ẹ̀yin orílẹ̀-èdè láti gbọ́,tẹ́tísílẹ̀ ẹyín ènìyànjẹ́ kí ayé gbọ́,àti ẹ̀kún rẹ̀,ayé àti ohun gbogbo tí ó ti inú un rẹ̀ jáde.

Àìsáyà 34

Àìsáyà 34:1-2