Àìsáyà 33:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wò ó, àwọn onígboyà ọkùnrin wọn pohùnréréẹkún ní òpópónà;àwọn ikọ̀ àlàáfíà ṣunkún kíkorò.

Àìsáyà 33

Àìsáyà 33:6-14