Àìsáyà 33:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun yóò jẹ́ ìpìlẹ̀ tí ó dájú fún àkókò rẹibùjókòó ìgbàlà kíkún àti ọgbọ́n òun ìmọ̀;ìbẹ̀rù Olúwa ni kọ́kọ́rọ́ sí ìṣúra yìí.

Àìsáyà 33

Àìsáyà 33:5-8