Àìsáyà 33:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí Olúwa ni onídàájọ́ wa, Olúwa ni olófin wa, Olúwa òun ni ọba wa;òun ni ẹni tí yóò gbà wá là.

Àìsáyà 33

Àìsáyà 33:15-24