Àìsáyà 32:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn àwọn oníwàdùwàdù ni yóò là tí yóò sì yè,àti ahọ́n tí ń kólòlò ni yóò là geerege.

Àìsáyà 32

Àìsáyà 32:1-9