Àìsáyà 32:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ènìyàn mi yóò máa gbé ní àlàáfíà ní ibùgbé àlàáfíà,ní àwọn ilé ààbò,ní àwọn ibi ìsinmi tí kò ti sí ìdíwọ́.

Àìsáyà 32

Àìsáyà 32:11-19