Àìsáyà 32:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èṣo òdodo náà yóò sì jẹ́ àlàáfíà;àbájáde òdodo yóò sì jẹ́ ìdákẹ́jẹ́ àti ìgbẹ́kẹ̀lé títí láé.

Àìsáyà 32

Àìsáyà 32:9-19