Àìsáyà 32:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ó lé díẹ̀ ní ọdún kanẹ̀yin tí ọkàn an yín balẹ̀ yóò wárìrì;ìkóórè àjàrà kò ní múnádóko,bẹ́ẹ̀ ni ìkóórè èṣo kò ní sí.

Àìsáyà 32

Àìsáyà 32:5-20