Àìsáyà 30:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohùn Olúwa yóò fọ́ Áṣíríà túútúú,pẹ̀lú ọ̀pá aládé rẹ̀ ni yóò lù wọ́n bolẹ̀.

Àìsáyà 30

Àìsáyà 30:25-33