Àìsáyà 30:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ègbé ni fún orílẹ̀-èdè alágídí náà,”ni Olúwa wí,“Fún àwọn tí ó gbé ètò jáde tí kì í ṣe tèmi,tí wọ́n ń gbìmọ̀ pọ̀, ṣùgbọ́n kì í ṣe nípa Ẹ̀mí mi,tí wọ́n ń dá ẹ̀ṣẹ̀ lórí ẹ̀ṣẹ̀;

Àìsáyà 30

Àìsáyà 30:1-7