Àìsáyà 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jérúsálẹ́mù ń ta gbọ̀n-ọ́n-gbọ̀n-ọ́nJúdà ń ṣubú lọ,ọ̀rọ̀ àti ìṣe wọn lòdì sí Olúwa,láti mú ojú ògo rẹ̀ bínú.

Àìsáyà 3

Àìsáyà 3:1-16