Àìsáyà 3:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ènìyàn yóò sì má a pọ́nọmọnìkejì wọn lójúẹnìkan sí ẹnìkejìi rẹ̀, aládùúgbòsí aládùúgbò rẹ̀.Àwọn ọ̀dọ́ yóò gbogun ti àwọn àgbà,àwọn mẹ̀kúnnù yóò dìde sí bọ̀rọ̀kìnní.

Àìsáyà 3

Àìsáyà 3:1-10