Àìsáyà 3:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa dojú ẹjọ́ kọàwọn alàgbà àti àwọn olórí àwọn ènìyàn rẹ̀.“Ẹyin ni ẹ ti run ọgbà àjàrà mi,ogún àwọn tálákà ń bẹ̀ nínú ilé yín.

Àìsáyà 3

Àìsáyà 3:8-21