Àìsáyà 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kíyèsí i, Olúwa, Olúwa àwọn ọmọ-ogun,fẹ́ mú ìpèsè àti ìrànlọ́wọ́ kúrò ní Jérúsálẹ́mù àti Júdàgbogbo ìpèsè ounjẹ àti ìpèsè omi

Àìsáyà 3

Àìsáyà 3:1-2