Àìsáyà 29:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́ẹ̀kan síi àwọn onírẹ̀lẹ̀ yóò yọ̀ nínú Olúwa:àwọn aláìní yóò yọ̀ nínú Ẹni Mímọ́ ti Ísírẹ́lì.

Àìsáyà 29

Àìsáyà 29:11-23