Àìsáyà 29:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ègbé ni fún ọ, Áríẹ́lì, Áríẹ́lì,ìlú níbi tí Dáfídì tẹ̀dó sí!Fi ọdún kún ọdúnsì jẹ́ kí àwọn àkọlùkọgbà àjọ̀dún un rẹ tẹ̀ṣíwájú.

Àìsáyà 29

Àìsáyà 29:1-6