Àìsáyà 28:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A kì í fi òòlù pa káráwétàbí kẹ̀kẹ́-ẹrù là á fi yí kúmínì mọ́lẹ̀;ọ̀pá ni a fi ń lu káráwé,àti kúmínì pẹ̀lú igi.

Àìsáyà 28

Àìsáyà 28:17-29