Àìsáyà 27:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ogun-jíjà àti lílé nílùú ni ófi dojú kọ ọ́pẹ̀lú ìjì gbígbóná ni ó lé e jáde,gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ tí afẹ́fẹ́ ìlà oorùn fẹ́

Àìsáyà 27

Àìsáyà 27:6-13