Àìsáyà 26:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn mi ń pòùngbẹẹ̀ rẹ ní ọ̀gànjọ́ òru;ní òwúrọ̀ ni ẹ̀mí mi ń ṣàfẹ́rí rẹ.Nígbà tí ìdájọ́ọ̀ rẹ bá sọ̀kalẹ̀ sórí ayéàwọn ènìyàn yóò kọ́ ìṣòdodo.

Àìsáyà 26

Àìsáyà 26:1-11