Àìsáyà 26:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa, Wọ́n wá sọ́dọ̀ rẹ nínú ìpọ́njúu wọn;nígbà tí o jẹwọ́n ní ìyà,wọ́n tilẹ̀ fẹ́ ẹ̀ má le gbàdúrà kẹ́lẹ́ kẹ́lẹ́.

Àìsáyà 26

Àìsáyà 26:10-21