Àìsáyà 25:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun yóò sì bi gbogbo ògiri gíga alágbára yín lulẹ̀wọn yóò sì wà nílẹ̀Òun yóò sì mú wọn wá si ilẹ̀,àní sí erùpẹ̀ lásán.

Àìsáyà 25

Àìsáyà 25:6-12