Àìsáyà 24:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òpópónà ni wọ́n ti ń kígbe fún wáìnìgbogbo ayọ̀ọ wọn ti di ìbànújẹ́,gbogbo àríyá ni a lé kúrò lórí ilẹ̀ ayé.

Àìsáyà 24

Àìsáyà 24:3-19